Monday, May 13, 2013

Profitclicking lede Yoruba Ere Tabua!



Sawari ohun ti....
o dara ti n saba sele si o!
·  Ijoba ile Amerika ti fi onte lu u pe won leto ati sowo pelu ami ase 6,578,010
·  O le bere pelu owo tasere Dola mewa ($10)ki o si di oloro repete pelu Dola mewa ti a o ya o lati bere eyi ti o tumo si pe ko na o ni ohun kankan lati bere!
·  Lojoojumo ti o ba ti wo inu eto wa tii se ipin tire ni inu re yoo maa dun nigbati o ba ri ere repete leyin ti o ba ti wo iwon ipolongo meta lojoojumo  
·  Opo eto ti o fara jo tiwa ni wan ti kogba wole leyin ojo die ti won si ti pa opolopo leku, elomiran donigbese nigbati won ko ri owo won gba jade       
·  Sugbon PROFIT CLICKING to de lati so o di olori rere  
·  Ø Saa ti mu elomiran wa ki o si gba idamewa ninu owo to ba fi ra iwon ipolowo
·  Ø So ara re di Olola ati Oloro nipa didara po mo wa ni PROFIT CLICKING

DA RA PO MO WA NIHIN-IN
http://www.profitclicking.com/join-form?r=ayodeb



BI A SE N SETO PROFITCLICKING:
 
Lati bere eto yi
O ni lati fi owo sinu apamo re.

Ra iwon ipolowo oja
O lee Ra iwon ipolowo oja ti o ba fe pelu iye owo ti o to Dola mewa fun iwon kan

Wo iwon ipolowo oja
O ni lati Wo iwon ipolowo lori intaneeti mefa lojoojumo ki o si gba ebun re lojoojumo

Ra IGBOKEGBODO 
Ma se ji ki o ya o lenu pe o lee dari ero si odo ara re. Pelu erongba pe ki awon eniyan lee dari si ileise re ki won si tesiwaju lati maa wa o nigbagbogbo. Otito naa ni pe gbogbo eniyan lo fe maa dari igbokegbodo sodo ara won ki awon eniyan si maa wa won ati ohun gbogbo ti won n se ri lori i ero komputa nipase ero ayelujara Lati odun 2004 ni a ti wa lori ikanni intaneeti ti opolopo ero si ti n da girigiri lori eto o wa ti olukuluku si n jere bi won ti fe. Pelu dola mewa, o lee dari ero to to egberun kan alejo sodo ara re..



DA RA PO MO WA NIHIN-IN
http://www.profitclicking.com/join-form?r=ayodeb



OHUN TOO GBODO SE LATI JE MULA PROFITCLICKING
Bere pelu dola mewa ti a o fun o lofe

RA IWON IPOLOWO OJA
Fun iwon ipolowo oja kookan ti o ba ra, iwo yoo gba toto silemeji owo dola ($0.20) lojoojumo laarin jale gbogbo ose.
Lati gbowo lojoojumo, o ni lati wo iwon ipolowo oja mefa mefa lojoojumo

E BA WA SORO

Ogbontagiri ninu owo Profitclicking ni mi lat odun 2012,  mo se setan lati ran o lowo lati kese jari ninu ise oloriire yiii. Boo ba ni awon ibeere ti a ko tii dahun nihin-in jowo kan si mi pelu eyikeyii ninu isofunni ti o wa nisale yii:


FaceBook:
Twitter: @ayodeb65
Skype: ayodeb

Call: +2348027336912, +234807066037172

tabi
Apoowe lori intaneeti mi niyi: ayodebconsult@gmail.com
 

1 comment:

  1. Eyi ma dara o. E jowo mo nilo alaye pupo sii nipa bi profitclicking se n sise. E seun.

    ReplyDelete